CONSULTAR A IFA


IJUBÁ IFÁ
- Rezar todas las vezes que sea necessário consultar Ifá, para no tener interferências negativas
OLOJO ONI MO JÚBÁ RE   /  OLUDAIYE MO JÚBÁ RE   / MO JÚBÁ OMODE MO JÚBÁ AGBA/   BI EKÒLÓ BA JÚBÁ ÍLÈ  /  ILÉ A LÀNU   /   KÍ IBA MI SEMO JÚBÁ ÀWON ÀGBÀ MÉRÌNDÍLÓGUN /    MO JÚBÁ BABA MI  /  MO TUN JÚBÁ AWON ÌYÁ MIMO JÚBÁ ÒRÚNMÌLÁ OGBAIYE GBÓRUN  /  OHÙN TI MO NA WI LOJO ONI / KORI BÉÉ FUN MI / JOWO MÁ JE KÌÍ DÍ MO  /  ÒNÀ KÌÍ DÍ MO  / OHUN TI A BA TI WI FUN OGBA L’OGBA NGBA  /  TI ÌLÁKÒSÉ NI SÉ LÁWUJÓ IGBIN  / TI EKESE NI NSE LAWUJÓ ÒWÚ   /  OLOJO ONÍ KOGBA ÒRÒ MI YÈWÒ YÈWO /   ASÉ ASÉ ASÉ
MERINDILOGUN
( Abrir consulta de merindilogun )


Ope ni fun Olorun

Iba a se ila oorun , mo juba

Iba a se iwo oorun , mo juba

Iba a se se ariwa , mo juba

Iba a se guusu, mo juba

Iba a se onile , kangun kangun orun, mo juba

Iba a se Esu, mo juba

Iba a se Ogun , mo juba

Iba a se Ossosi, mo juba

Iba a se Sango, mo juba

Iba a se Yemoja, mo juba

Iba a se Oshun, mo juba

Iba a se Oya, mo juba

Iba a se Oke, mo juba

Iba a se Orisa Oko, mo juba

Iba a se Agayu, mo juba

Iba a se Olokun, mo juba

Iba a se Inle, mo juba

Iba a se Abata, mo juba

Iba a se Ina, mo juba

Iba a se Aje, mo juba

Iba a se Orunmila, mo juba

Iba (PADRINO/A) Kikan Mase

Iba (YUBOGNA/O) Kikan Mase

Iba  ( BABALAWOS PRESENTES ) Kikan Mase

Iba gbodipete  /  Iba okuta  /  Iba loko


Bi ekolo ba juba ile ile a lanu  / 
Omode ki ijuba ki iba pa a

To ase si ni lenu morere mi o  /   Ase .







ORIKI para pasar la responsabilidad al cliente por no hacer el ebbo, después de la consulta.

Oruko awon
Orisi ifa miran
Toua nike yoruba ti o ia tosi
Orunmila mi abiba
Oobi unle olokun


(Invocación para pedir el perdón del consultante y que no se le exija ninguna ofrenda cuando el awo está haciendo su adivinación a esa persona)


Orunmila mo pe, orunmila mo pe, orunmila mo pe  /  ifa mo pe, ifa mo pe, ifa mo pe /  oduduwa mo pe, oduduwa mo pe, oduduwa mo pe  / igi nla subu wonakankan d’ etu, orunmila ni o di adariji /  mo ni o di adariji. O ni bi oya ba pa ni tan /  a ki i, a sa a, a f’ ake eran fun u. a dariji o ni bi sango ba pa ni tan / a ki i, a sa, a f’ agbo fun u. a dariji, o ni bi ogun ba pa ni tan /  a ki i, a sa a, a f’ a ja fun u /  a dariji, oduduwa dariji wa bi a ti ndariji awon ti o se wa. Ase.